Oga awon onimoto nipinle Eko, MC Oluomo fun awon ebi Mohbad ni milionu marun-un Naira
Alaga egbe awon onimoto nipinle Eko, Alaaji Musilu Akinsanya Mc Oluomo ti fi owo tiye re je milionu marun-un Naira ta awon ebi gbajumo olorin takasufee, Mohbad lore.
Gege bi a se gbo, oga awon onimoto yii fun omo Mohbad iyen, Light ni milionu meta Naira, to si fun iya ati baba omodekunrin to ku naa milionu kookan Naira.
Latigba tiroyin ohun ti kan awon eeyan lara ni won ti n ka saara si Olu ilu
Comments
Post a Comment