Oba Ara sedaro Mohbad, o ni ibanuje niku e je fun wa

 Gbajúgbajà olorin emi nni, Ajiyinrere Rotimi Onimole ti gbogbo aye mo si Oba Ara ti kedun pelu àwon ebi odomode olorin takasufee to dologbe, Mohbad.

Oba Ara ogbe okan àti ibanuje nla ni ilu Mohbad jé fun gbogbo wa, ogo nla lo wokuu lojiji.

Àdúrà mi nipe ki Olorun ba wa fori ji I, ko ba wa dekun ibanuje, ko si ba wa duro ti gbogbo ebi to fi sile lo. A fe o, Olorun fe o ju wa lo.

Comments

Popular posts from this blog

Ipo Awujalẹ gbọdọ waye nipasẹ aṣa ati ilana ilẹ Ijẹbu ki i ṣe nipa oṣelu- Ọtunba Rotimi Paṣeda

Nitori GNI: Awọn Yewa lawọn ko le ta ogun ibi wọn fun Yayi lọdun 2027

Ojiṣẹ lṣẹdalẹ ṣatupalẹ ewi Wọle Ṣoyinka, Abiku si ede Yoruba.