Oga awon onimoto nipinle Eko, MC Oluomo fun awon ebi Mohbad ni milionu marun-un Naira


Alaga egbe awon onimoto nipinle Eko, Alaaji Musilu Akinsanya Mc Oluomo ti fi owo tiye re je milionu marun-un Naira ta awon ebi gbajumo olorin takasufee, Mohbad lore.

Gege bi a se gbo, oga awon onimoto yii fun omo Mohbad iyen, Light ni milionu meta Naira, to si fun iya ati baba omodekunrin to ku naa milionu kookan Naira.
Latigba tiroyin ohun ti kan awon eeyan lara ni  won ti n ka saara si Olu ilu

Comments

Popular posts from this blog

Ipo Awujalẹ gbọdọ waye nipasẹ aṣa ati ilana ilẹ Ijẹbu ki i ṣe nipa oṣelu- Ọtunba Rotimi Paṣeda

Nitori GNI: Awọn Yewa lawọn ko le ta ogun ibi wọn fun Yayi lọdun 2027

Ojiṣẹ lṣẹdalẹ ṣatupalẹ ewi Wọle Ṣoyinka, Abiku si ede Yoruba.